About olamide

Welcome text

Thursday, 10 July 2014

Lyrics: Ibadan - Q-Dot ft Olamide

Bi sekere ba ti dun oo
Konga a te le
A te le
Ijo ma tele
Antrans ko gi le o fun mi jaree

Verse 1:
Lateko de challengi
A gba guru mara ji
Awole pelu bugati
Ankara lori fasasi
Idi n be nibadan o
Oke be nibadan o
Idi arere idi ayunre
Oke sango oke mo po
Ema je ko di ja
Olosho yapa ni bodija o
Pelu sokoto pe n pe
Awon omo mi ni mo lete
Ema soko fun eye twitter
Alomo metta feya speaker
Furo rabata fe ya bumber
Them say them to buggi down

Chorus:
Ibadan ni mo wa o
Ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o
Ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le
Ibadan ni mo wa oo

Verse 2: (Olamide)
E shoutout si awon omo uni
Leed city de badan poly
Ebami ki kunle silencer
Omo musulumi to fa poli
Ero to lo london
Ebami ki tayo dekida
Tiringbeku teletele
Omo ibadan to di nigga
Omo woli to n fa taba
Basira su sara ko ta ba
Omugo fe high ogun lada
Won de ni momo re feya fada
Qdot fe silekun fe kun
O yo tan owa be kun bekun
I turn up tan osi seku
Ka to fi embivadale le odi seven

Chorus:
Ibadan ni mo wa o
Ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o
Ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le
Ibadan ni mo wa oo

Verse 3:
Ni le oluyole ooo
Awon omo lagelu
Ujo sokky mo gbe wa o
No be skelewu
Atana wole pelu sanpeni
Ki ni a de temi complaini
Pe owo afefe la fi sustaini
Ahhen ti naira ba ti tan
Mabinu ma ko pounsi jade
Ko fun mi lolosho to wo gown
Won fun mi lorogbo to ti brown
Eyi ko lemaso fun wa
Pe oshogbo ti di town
Eeeeen we rocking gucci gucci
Ajoko sori chair kusin
Eran chikin la gbe ah nu jawee

No comments:

Post a Comment